Emi ori iru olorun eyi ri free mp3 download






















O gba ki akeeko ni imo kikun nipa owo eyin. E je ki a woe to aroko yii:. Koseemanii ni owo je fun eda. Owo ni ohun ti a n na tabi fi ra nnkan. Ire meta ni eda n wa ni ile aye, bi Ifa, elerii-ipin se la a sile. Awon ire meta naa ni ire owo, ire omo, ire aiku tabi alaafia pari iwa.

Awa n wowo o,. Awa n womo,. Awa n wa atunbotan aye. Eni ti o ba lowo yoo niyawo, yoo kole, yoo si ni aso. Idi niyi ti owo fi je egbon fun gbogbo ire yooku. Ni orile ede Naijiria, owo Naira ati Kobo ni a n na. Ojuse pataki kan ti a mo on mo niyi. O le kole alaruru, o le ra obokun-oloye, o le fe iyawo. Owo ni a fi n se ohun gbogbo. Gbajumo olorin kan tile tusu de idi ape ninu orin re yii:. Ile lo n gbe. Nile aye ta wa yii. Owo ni n se nnkan gidi.

Bi owo se se pataki to, tolori telemu ni n wa a kiri. Kaakiri agbaye ni awon eniyan ti n sare owo. Orisiirisii owo lo wa. Owo tutu ati owo gbigbona. Owo ti a fi oogun oju eni ko jo ni a mo si owo tutu. Owoo-gbona ni owo won fi ona eru ko jo. Ohun ni won tun n pen i owo eje, owo okuta ati bee bee lo.

Okan-o-jokan ipede awon Yoruba fi pataki owo han. Owo a maa fun eniyan ni iyi. Ojuse owo kan niyi. Awon Yoruba a maa fi owo ra iyi. Owo ni a fi n pinle owo, ola ati ola. Opomulero ni owo je fun owo. Owo okuta tumo si owo ti ki i duro lowo. Oye owo ti a bar a oja n so bi a o se karamaasiki nnkan naa si. Bi a ko ba fi owo ra nnkan, a ki i mo iyi iru nnkan bee. Oro agba niyi. Orisiirisii ona ni eda fi wa owo. Ese si ni gbogbo iwonyi lodo Olorun. O ko o pe:. Yesi, otito ni. Aini owo baba ijaya.

Alowo lowo, baba afojudi. Yesi, otito ni…….. Bi aoko ajemo-sispaya, a ri oniruuru oruko ti a n pe owo, oriki, iwulo, anfaani ati alebu re. Ni ile Yoruba, awon eko ti awon obi maa n ko omo lati kekere ni a n pe ni eko — ile. Omo ti won ko, to si gba, to si n mu eko naa lo nigba gbogbo ni a n pe ni omoluabi. Olu-iwa ni eni ti o je orisun gbogbo iwa rere aye. Bi enikeni ba si je omo re, oluwa re ko ni sai ni ekun iwa rere; eni ti o ko gbogbo iwa rere po, ti gbogbo elegbe ati olugba ka si ojulowo eniyan.

Abuda omoluabi po jantirere. Ara re ni owo, iteriba fun agba, osise, oninuure, onisuuru, eni ti ko je huwa abosi tabi ireje si enikeji. Awon ona ti omode le gba huwa omoluabi niwonyi:. Eyi ni pe, omode to ba ni iwa pele ati iwa rere yoo ma aba awon agba rin.

Oniruuru iwa rere ni omode le hu si agba. Ekini ninu won ni ibowo fun agba. Omokomo ti o ba daa an wo, iya ni iru won n je. Ona keji ni pe, bi agbalagba ba n soro, omode ko gbodo pariwo tabi se ayonuso si oro ti agba ba n so. Ni ile Yoruba, omode to gbeko ki i da si oro ti won ko pe e si.

Oba tin ti ilekun teni kan ole shi Ogbo ti kii-ti Omini mini tin mi ile aye Okunrin ogun…Erin lakatabu Ogbamu gbamu oju orun oshe gbamu Kiniun eyaa Judah, ekun oko Faraoh.

Gbongbo idile Jesse Eleyinju ina, Inajojo, Eru Jojo Ashoro kolu bii ogiri gbigbe Oba tin san lawo sanma ti awon alaimokan npe ni sango Abiyamo lojo ija, abiyamo lojo ishoro Kabiesi ti awon agba agba merin le logun foribale fun, ti won ke mimo, mimo, mimo Eleyinjuana oba tio ngba okan irora lowo ibanuje Alamo tin mo ori eda Atori ina tina satani sare Baba mimo, Omo mimo, Emi mimo Oba to ngbe nu wundia shola, oro gbe inu omo eniyan foun Ariiro ala!

Oba to gbe iku mi nii isegun,. Obiriikiti oba to kpa oko iku da laye Eleti gbaroye eda Arewa ti n be lorun, oba waa, oba woo, oba wawa wowo Pari pari ola. Oda da, to da gbogbo aye, ologo didan O gbi gba ti ngba alai lara Oka soso adaba ti nmi igbo kiji kiji Omi mo to mo iye awa eda to da Egbo lehin eni ada loro. A ko ma ti ika lehin Oba nla ti nfi ola wo ni bi aso Otiti nla ato fi ara ti bi oke Ounje nla ato fi bori ibi Baba mi, oro nla ojo nla tobori Ogbele Oba nti je emi ni lojo gbogbo Eru Jeje ti nbe leti okun pupa Oju kan nti wo igba aye Olorun ajulo, atobiju iba re Aye ka o won ko ri e ka Aye wa o titi wo ko ri o Won ba e nibi toju gbogbo aye lo Eni ti o se ohun ti o tobi, ti a ko le se awari Ohun iyanu laini iye Oba aiku airi Orisun ogbon Olubukun julo Ologo julo iba re Olorun ti ki rin irin ajo Okan naa loni, okan naa lana, oba titi ayeraye Oyigiyigi -Atobiju oba iyanu -Ologo mimo julo.

Adagba ma tepa ojo Adagba ma paro oye A ja segun. Oba ti ko ni ibere ti ko si lopin Kaabiyesi ooooooo. Oba awon oba. Can You please attach an audio clip of this Oriki so one can appreciate the accent and pronunciation Of the words, thanks. He who work for God shall never lack. God almighty will grant you more understanding in Jesus name.

An audio with this will be more blessings. Pls can the audio be attached? Thank you. Great work done bro! Keep up the good work. Counting my blessing oh, mo chache, Moun gbowo Blessing on blessing oh, mo chache, Moun gbowo. Counting my blessing oh, mo chache, Moun gbowo Blessing on blessing oh, mo chache, Moun gbowo mi oh. Olowo la ye mo Put your money where your mouth is, If you want to say something ko fi owo se mouthpiece, I used to be broke but thank God that i find peace, Mimi kan o le mi mi laye yi me i stand fit.

Chache - Ola Dips.



0コメント

  • 1000 / 1000